Dáníẹ́lì 4:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lórí ibùsùn mi, mo rí ìran náà, olùṣọ́ kan dúró ṣíwájú u mi, àní ẹni mímọ́ kan, ó ń bọ̀ wá láti ọ̀run

Dáníẹ́lì 4

Dáníẹ́lì 4:8-22