Dáníẹ́lì 4:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ìran náà tí mo rí nígbà tí mo wà lórí ibùsùn mi, mo rí igi kan láàrin ayé, igi náà ga gidigidi.

Dáníẹ́lì 4

Dáníẹ́lì 4:8-19