Dáníẹ́lì 3:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni a kéde kígbe sókè wí pé, “Ohun tí a paláṣẹ fún un yín láti ṣe nìyìí, gbogbo ènìyàn, orílẹ̀ èdè àti èdè gbogbo:

Dáníẹ́lì 3

Dáníẹ́lì 3:2-14