Dáníẹ́lì 3:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó sì pàṣẹ fún àwọn alágbára nínú ogun rẹ̀ pé, kí wọ́n de Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dinígò, kí wọn sì jù wọ́n sínú iná ìléru.

Dáníẹ́lì 3

Dáníẹ́lì 3:11-25