Dáníẹ́lì 3:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dinígò dá ọba lóhùn wí pé, “Nebukadinéṣárì, kì í ṣe fún wa láti gba ara wa sílẹ̀ níwájú u rẹ nítorí ọ̀rọ̀ yìí.

Dáníẹ́lì 3

Dáníẹ́lì 3:15-20