Dáníẹ́lì 2:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba dá àwọn awòràwọ̀ lóhùn pé, “Ohun náà ti kúrò lórí mi: tí ẹ̀yin kò bá sọ àlá náà àti ìtumọ̀ rẹ̀ fún mi, èmi yóò gé e yín sí wẹ́wẹ́, ilé e yín yóò sì di ààtàn.

Dáníẹ́lì 2

Dáníẹ́lì 2:1-6