Dáníẹ́lì 2:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ní ọwọ́ rẹ ló fi gbogbo ènìyàn, àwọn ẹranko ìgbó àti ẹyẹ ojú ọ̀run sí. Ní ibi gbogbo tí wọ́n ń gbé, ó ti fi ọ́ ṣe olórí i wọn. Ìwọ ni orí i wúrà náà.

Dáníẹ́lì 2

Dáníẹ́lì 2:31-41