Dáníẹ́lì 2:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó ṣe ń wò, òkúta kan wá, tí kò wá láti ọwọ́ ẹnìkankan. Ó kọlu ère náà ní àtẹ́lẹṣẹ̀ irin àti amọ̀, ó sì fọ́ wọn sí wẹ́ẹ́wẹ́.

Dáníẹ́lì 2

Dáníẹ́lì 2:30-39