Dáníẹ́lì 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó sọ fún wọn pé, “Mo ti lá àlá kan èyí tí ó mú kí ọkàn mi dàrú, mo sì fẹ́ mọ ìtumọ̀ àlá náà.”

Dáníẹ́lì 2

Dáníẹ́lì 2:1-12