Dáníẹ́lì 2:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo dúpẹ́, mo sì fi ìyìn fún ọ, ìwọ Ọlọ́run àwọn baba mi:ó ti fún mi ní ọgbọ́n àti agbáraó ti fi àwọn nǹkan tí a bèrè lọ́wọ́ rẹ̀ hàn fún minítorí tí ìwọ ti fi àlá ọba hàn wá.”

Dáníẹ́lì 2

Dáníẹ́lì 2:18-32