Dáníẹ́lì 2:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òru, àsírí náà hàn sí Dáníẹ́lì ní ojú ìran. Nígbà náà ni Dáníẹ́lì fi ògo fún Ọlọ́run ọ̀run

Dáníẹ́lì 2

Dáníẹ́lì 2:17-29