Dáníẹ́lì 2:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nǹkan tí ọba béèrè yìí ṣòro púpọ̀. Kò sí ẹni tí ó lè fi han ọba à fi àwọn òrìṣà, tí wọn kì í gbé láàrin ènìyàn.”

Dáníẹ́lì 2

Dáníẹ́lì 2:9-16