Dáníẹ́lì 12:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi gbọ́, ṣùgbọ́n kò yé mi. Nígbà náà ni mo bèèrè pé, “Olúwa mi, kí ni yóò jẹ́ àbábọ̀ àwọn nǹkan wọ̀nyí?”

Dáníẹ́lì 12

Dáníẹ́lì 12:1-9