Dáníẹ́lì 12:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Láti àkókò tí a ó mú ẹbọ ojoojúmọ́ kúrò, tí a ó sì gbé ìríra tí ó ń fa ìsọdahoro kalẹ̀ yóò sì jẹ́ ẹgbẹ̀rún àti igba lé àádọ́rùn-ún ọjọ́ (1,290).

Dáníẹ́lì 12

Dáníẹ́lì 12:2-13