Dáníẹ́lì 11:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì pàgọ́ ọ rẹ̀ láàrin òkun kọjú sí àárin òkè mímọ́ ológo Síbẹ̀ yóò wá sí òpin rẹ̀, ẹnìkan kò ní ràn-án lọ́wọ́.

Dáníẹ́lì 11

Dáníẹ́lì 11:40-45