Dáníẹ́lì 11:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lára àwọn tí ó mòye yóò kọsẹ̀, nítorí kí a baà tún wọn ṣe, wọ́n di mímọ́ àti aláìlábàwọ́n títí di ìgbà ìkẹyìn nítorí yóò sì wá ní àkókò tí a yàn.

Dáníẹ́lì 11

Dáníẹ́lì 11:32-39