Dáníẹ́lì 11:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àwọn tí ó mòye yóò máa kọ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀, ṣùgbọ́n fún ìgbà díẹ̀, wọn yóò máa ṣubú nípa idà tàbí kí a jó wọn tàbí ìgbèkùn tàbí nípa ìkógún.

Dáníẹ́lì 11

Dáníẹ́lì 11:29-39