Dáníẹ́lì 11:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹni tí kò níláárí kan yóò rọ́pò rẹ̀, ẹni tí a kò tí ì fi ọlá ọba fún rí. Yóò sì gbógun sí ìjọba nígbà tí ọkàn àwọn ènìyàn balẹ̀ láìbẹ̀rù, yóò sì gbà á pẹ̀lú àrékérekè.

Dáníẹ́lì 11

Dáníẹ́lì 11:18-27