Dáníẹ́lì 11:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ọba àríwá yóò lọ kó ogun mìíràn jọ, tí ó pọ̀ ju ti àkọ́kọ́ lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún, yóò jáde pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ogun tí ó ti dira ogun fún dáradára.

Dáníẹ́lì 11

Dáníẹ́lì 11:11-16