Dáníẹ́lì 10:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo wo òkè, mo rí ọkùnrin kan tí ó wọ aṣọ àlà funfun, pẹ̀lú àmùrè wúrà dáradára ni ó fi di ẹ̀gbẹ́.

Dáníẹ́lì 10

Dáníẹ́lì 10:4-15