Dáníẹ́lì 10:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìsinsinyí mo wá láti ṣàlàyé ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ sí àwọn ènìyàn rẹ ní ọjọ́ iwájú, nítorí ìran náà ń sọ nípa ọjọ́ iwájú.”

Dáníẹ́lì 10

Dáníẹ́lì 10:10-20