Dáníẹ́lì 1:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lára àwọn wọ̀nyí ni àwọn tó wá láti Júdà: Dáníẹ́lì, Hananíáyà, Mísáẹ́lì àti Ásáríyà.

Dáníẹ́lì 1

Dáníẹ́lì 1:3-13