Àwọn Hébérù 9:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kì í si i ṣe pé kí ó lè máa fi ara rẹ̀ rúbọ nígbàkúgbà, bí olórí àlùfáà tí máa ń wọ inú ibi mímọ́ lọ lọ́dọọdún ti oun pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ ti kì í ṣe tirẹ̀;

Àwọn Hébérù 9

Àwọn Hébérù 9:22-28