Àwọn Hébérù 8:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúkúlùkù kò ní tún máa kọ́ ara ìlú rẹ̀,tàbi olukulùkù arákùnrin rẹ̀, pé, ‘mọ Olúwa,’Nítorí pé gbogbo wọn ni yóò mọ̀ mí,láti kékere dé àgbà.

Àwọn Hébérù 8

Àwọn Hébérù 8:3-13