Àwọn Hébérù 6:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ti ẹ̀kọ́ àwọn bamitísìmù, àti ti ìgbọ́wọ́-léni, ti àjíǹde òkú, àti tí ìdájọ́ àìnípẹ̀kun.

Àwọn Hébérù 6

Àwọn Hébérù 6:1-10