Àwọn Hébérù 6:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú èyí tí Ọlọ́run, ẹni tí ń fẹ́ gidgidi láti fi àìlèyípadà ète rẹ̀ hàn fún àwọn ajogún ìlérí náà, ó fi ìbúra sáàrin wọn.

Àwọn Hébérù 6

Àwọn Hébérù 6:9-20