Àwọn Hébérù 6:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwá sì fẹ́ kí olúkúlùkù yín máa fi irú àìsinmi kan náà hàn, fún ẹ̀kún ìdánilójú ìrètí títí dé òpin:

Àwọn Hébérù 6

Àwọn Hébérù 6:3-20