Àwọn Hébérù 5:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí òun tilẹ̀ ń ṣe Ọmọ Ọlọ́run, síbẹ̀ ó kọ́ gbọ́ràn nípa ohun tí ó jìyà rẹ̀;

Àwọn Hébérù 5

Àwọn Hébérù 5:1-10