Àwọn Hébérù 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ má ṣe sé ọ̀kan yin le,bí ìgbà ìṣọ̀tẹ̀,bí i ní ọjọ́ ìdánwò ní ihà:

Àwọn Hébérù 3

Àwọn Hébérù 3:1-16