Àwọn Hébérù 3:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ kíyèsára, ará, kí ọkàn búburú ti àìgbàgbọ́ má ṣe wà nínú ẹnikẹ́ni yín, ní lílọ kúrò lọ́dọ̀ Ọlọ́run alààyè.

Àwọn Hébérù 3

Àwọn Hébérù 3:4-17