Àwọn Hébérù 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ dá a ní onírẹ̀lẹ̀ díẹ̀ ju àwọn ańgẹ́lì lọ;ìwọ fi ògo àti ọlá de e ni adé,ìwọ sì fi í jẹ olórí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ:

Àwọn Hébérù 2

Àwọn Hébérù 2:2-8