Àwọn Hébérù 2:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wí pé,“Èmi ó sọ̀rọ̀ orúkọ rẹ̀ fún àwọn ará mi,ni àárin ìjọ ni èmi yóò kọrin ìyìn rẹ̀.”

Àwọn Hébérù 2

Àwọn Hébérù 2:3-13