Àwọn Hébérù 13:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ìgbéyàwó lọ́lá láàrin gbogbo ènìyàn, kí àkéte si jẹ́ aláìléérí: Nítorí àwọn àgbérè àti àwọn panṣágà ni Ọlọ́run yóò dá lẹ̀jọ́.

Àwọn Hébérù 13

Àwọn Hébérù 13:1-12