Àwọn Hébérù 12:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ máa ní sùúrù lábẹ́ ìbáwí: Ọlọ́run bá wa lò bí ọmọ ni; nítorí pé ọmọ wo ni ń bẹ ti baba kì í báwí?

Àwọn Hébérù 12

Àwọn Hébérù 12:3-9