Àwọn Hébérù 12:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ẹ̀yin mọ pé lẹ̀yìn náà, nígbà tí ó fẹ láti jogún ìbùkún náà, a kọ̀ ọ́, nítorí kò ri àyè ìronupìwàdà, bí o tilẹ̀ kẹ pé ó fi omijé wa a gidigidi.

Àwọn Hébérù 12

Àwọn Hébérù 12:13-21