Àwọn Hébérù 11:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ìgbàgbọ́ ní Ábúráhámù, nígbà tí a ti pé e láti jáde lọ sí ibi tí òun yóò gbà fún ilẹ̀ ìní, ó gbọ́, ó sì jáde lọ, láì mọ ibi tí òun ń rè.

Àwọn Hébérù 11

Àwọn Hébérù 11:3-18