Àwọn Hébérù 11:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ìgbàgbọ́ ni o kọ Éjípítì sílẹ̀ láìbẹ̀rù ìbínú ọba: nítorí tí o dúró ṣinṣin bí ẹni tí ó n ri ẹni àìrí.

Àwọn Hébérù 11

Àwọn Hébérù 11:18-36