Àwọn Hébérù 11:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó kúkú yàn láti máa ba àwọn ènìyàn Ọlọ́run jìyà, ju jíjẹ fàájì ẹ̀ṣẹ̀ fún ìgba díẹ̀.

Àwọn Hébérù 11

Àwọn Hébérù 11:17-31