Àwọn Hébérù 10:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí kò ṣe bẹ́ẹ̀, a kì ìbá tí dẹ́kun àti máa rú wọn, nítorí àwọn ti ń sìn ki ìbá tí ní ìmọ̀ ẹ̀ṣẹ̀, nígbà tí a ba ti wẹ̀ wọ́n mọ́ lẹ̀ẹ̀kanṣoṣo.

Àwọn Hébérù 10

Àwọn Hébérù 10:1-9