Àwọn Hébérù 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí kò sí ọ̀kan nínú àwọn ańgẹ́lì tí Ọlọ́run fi ìgbà kan sọ fún pé:“Ìwọ ni ọmọ mi;lónì- ni mo bí ọ”?Àti pẹ̀lú pé;“Èmi yóò jẹ́ baba fún-un,Òun yóò sì jé ọmọ mi”?

Àwọn Hébérù 1

Àwọn Hébérù 1:2-10