Àwọn Hébérù 1:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní kíká ni ìwọ yóò ká wọn bí aṣọ,bí ìpàrọ̀ aṣọ ni a ó sì pàárọ̀ wọn.Ṣùgbọ́n ìwọ fúnrarẹ kì yóò yípadààti pé ọdún rẹ kì yóò ní òpin.”

Àwọn Hébérù 1

Àwọn Hébérù 1:4-14