Ámósì 8:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọjọ́ ń bọ̀,” ni Olúwa Ọlọ́run wí,“nígbà tí èmi yóò rán ìyàn sí ilẹ̀ náà,kì í ṣe ìyàn oúnjẹ tàbí òùngbẹ fún omi.Ṣùgbọ́n ìyàn gbígbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa.

Ámósì 8

Ámósì 8:3-14