Èyí ni ohun ti Olúwa Ọlọ́run fi hàn mí: Olúwa Ọlọ́run ń pè fún ìdájọ́ pẹ̀lú iná; ó jó ọ̀gbun ńlá rún, ó sì jẹ ilẹ̀ run.