Ámósì 6:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí Olúwa Ọlọ́run alágbára wí pé,“Èmi yóò gbé orílẹ̀-èdè kan dìde sí ọ ìwọ Ísírẹ́lì,tí yóò máa ni ọ́ lára ní gbogbo ọ̀nàláti ẹnu ọ̀nà ìwọlé Hámátì títí dé àfonífojì aginjù.”

Ámósì 6

Ámósì 6:8-14