Ámósì 5:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọlọgbọ́n máa ń dákẹ́ jẹ́ẹ́ ní àkókò wọ̀nyíNítorí búburú ni gbogbo ọjọ́.

Ámósì 5

Ámósì 5:8-23