Ámósì 5:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ìwọ ilé Ísírẹ́lì, ìpohùnréré ẹkún tí mo ṣe nípa rẹ:

Ámósì 5

Ámósì 5:1-3