Ámósì 4:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mo ti bì ṣubú nínú yín,bí Ọlọ́run ti bi Sódómù àti Gòmórà ṣubúẹ̀yin sì dàbí ògúnná tí a fò yọ kúrò nínú ìjóná,ṣíbẹ̀ ẹ̀yin kò yípadà sí mi,”ni Olúwa wí.

Ámósì 4

Ámósì 4:5-13