Ẹ kéde ní ààfin Áṣídódùàti ní ààfin ní ilẹ̀ Éjíbítì.“Ẹ kó ara yín jọ sí orí òkè ńlá Samáríà;Kí ẹ sì wo ìrọ́kẹ̀kẹ̀ ńlá láàrin rẹ̀àti ìnílára láàrin àwọn ènìyàn rẹ.”