Ámósì 3:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ ẹyẹ ṣubú sínú okùn ọdẹ lórí ilẹ̀nígbà tí a kò dẹ okùn ọdẹ fún un?Okùn ọdẹ ha lè hù jáde lórí ilẹ̀nígbà tí kò sí ohun tí yóò mú?

Ámósì 3

Ámósì 3:3-13