Ámósì 3:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gbọ́ èyí kí o sì jẹ́rìí nípa ilé Jákọ́bù,” ni Olúwa wí, Olúwa Ọlọ́run alágbára.

Ámósì 3

Ámósì 3:4-15